Home Page
cover of JỌLÁ ÀTI OYÍNKÁN
JỌLÁ ÀTI OYÍNKÁN

JỌLÁ ÀTI OYÍNKÁN

Ilesanmi MoyinoluwaIlesanmi Moyinoluwa

0 followers

00:00-01:18

Mo láyọ̀ láti fi tó yín létí pé Jọlá àti Oyínkán ti parí sáà ẹ̀kọ́ kan ní 23/1/2025. Ní sáà ẹ̀kọ́ tó parí náà, àwọn ohun tí wọ́n kọ́ ni orúkọ àwọn ibìkan àti àwọn ohun ìrìnsẹ̀, wọ́n si ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìkúrọ̀sọ nípa wọn, mo sì ní àrídájú pé èyí ran ọ̀rọ̀ síṣọ wọn lọ́wọ́. Wọ́n kọ́ oríṣi àwọn ìhun èdè tí a máa ń lò nínú ìtàkúrọ̀sọ láti so gbólóhùn papọ̀, a sì lò wọ́n láti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìkúrọ̀sọ. Wọ́n kọ́ díẹ̀ lára àwọn ọ̀rọ̀ tó nííṣe pẹ̀lú ojú ọjọ́ àti àsìkò, a ṣe àtúnyẹ̀wò ẹ̀kọ́ lórí òǹkà...

All Rights Reserved

You retain all rights provided by copyright law. As such, another person cannot reproduce, distribute and/or adapt any part of the work without your permission.

Audio hosting, extended storage and much more

MORE INFO

Listen to JỌLÁ ÀTI OYÍNKÁN by Ilesanmi Moyinoluwa MP3 song. JỌLÁ ÀTI OYÍNKÁN song from Ilesanmi Moyinoluwa is available on Audio.com. The duration of song is 01:18. This high-quality MP3 track has 1449.652 kbps bitrate and was uploaded on 2 Feb 2025. Stream and download JỌLÁ ÀTI OYÍNKÁN by Ilesanmi Moyinoluwa for free on Audio.com – your ultimate destination for MP3 music.

TitleJỌLÁ ÀTI OYÍNKÁN
AuthorIlesanmi Moyinoluwa
CategoryRecording
Duration01:18
FormatAUDIO/X-WAVPACK
Bitrate1449.652 kbps
Size14.23MB
Uploaded2 Feb 2025

Listen Next

Other Creators