Home Page
cover of ÌGBÀ NI GBOGBO NǸKÁN
ÌGBÀ NI GBOGBO NǸKÁN

ÌGBÀ NI GBOGBO NǸKÁN

Ilesanmi MoyinoluwaIlesanmi Moyinoluwa

0 followers

00:00-00:38

kò sí bí òkè kan ti lè ga tó gígùn ún dé téńté orí ẹ̀, bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ìṣísẹ̀ àkọ́kọ́ ìṣísẹ̀ kọ̀ọ̀kan tí a kò kà sí, ní ń darapọ̀ di ìgbésẹ̀ kan ńlá tí gbogbo ayé leè rí! nítorí náà ńkọ́? kò sígbà tó kéré kò sákòókò tí kò wúlò Ìṣẹ́jú aago kọ̀ọ̀kan Ló níṣẹ́ tó ń ṣe Má fàkókò ṣeré ó, Ọ̀rẹ́ wa.

Audio hosting, extended storage and much more

AI Mastering

Transcription

Kosibi yoke konti le e gato. Gigun deten te orie. Bere pelun ishi se akoko. Ishi se kokon se akokasi. Nin dara podi ibe se kanla. Sigu guwaye le e ri. Ni torina onko. Kosibi asokere. Kosa koko tiko ubulo. Ise dua goko okon. Loni se tonishi. Mafia koko shireu. Orewa.

MORE INFO

Listen to ÌGBÀ NI GBOGBO NǸKÁN by Ilesanmi Moyinoluwa MP3 song. ÌGBÀ NI GBOGBO NǸKÁN song from Ilesanmi Moyinoluwa is available on Audio.com. The duration of song is 00:38. This high-quality MP3 track has 1165.339 kbps bitrate and was uploaded on 20 Apr 2023. Stream and download ÌGBÀ NI GBOGBO NǸKÁN by Ilesanmi Moyinoluwa for free on Audio.com – your ultimate destination for MP3 music.

TitleÌGBÀ NI GBOGBO NǸKÁN
AuthorIlesanmi Moyinoluwa
CategoryPodcast
Duration00:38
FormatAUDIO/X-WAVPACK
Bitrate1165.339 kbps
Size5.66MB
Uploaded20 Apr 2023

Listen Next

Other Creators